Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kor 7:34 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iyatọ si wà pẹlu larin obinrin ti a gbe ni iyawo ati wundia. Obinrin ti a kò gbe ni iyawo a mã tọju ohun ti iṣe ti Oluwa, ki on ki o le jẹ mimọ́ li ara ati li ẹmí: ṣugbọn ẹniti a gbé ni iyawo a ma tọju ohun ti iṣe ti aiye, bi yio ti ṣe le wù ọkọ rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. Kor 7

Wo 1. Kor 7:34 ni o tọ