Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kor 7:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn bi iwọ ba si gbeyawo, iwọ kò dẹṣẹ: bi a ba si gbé wundia ni iyawo, on kò dẹṣẹ. Ṣugbọn irú awọn wọnni yio ni wahalà nipa ti ara: ṣugbọn mo dá nyin si.

Ka pipe ipin 1. Kor 7

Wo 1. Kor 7:28 ni o tọ