Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kor 5:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ẹ mu iwukara atijọ kuro ninu nyin, ki ẹnyin ki o le jẹ́ iyẹfun titun, gẹgẹ bi ẹnyin ti jẹ́ aiwukara. Nitori a ti fi irekọja wa, ani Kristi, rubọ fun wa.

Ka pipe ipin 1. Kor 5

Wo 1. Kor 5:7 ni o tọ