Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kor 4:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina, ẹ máṣe ṣe idajọ ohunkohun ṣaju akokò na, titi Oluwa yio fi de, ẹniti yio mu ohun òkunkun ti o farasin wá si imọlẹ, ti yio si fi ìmọ ọkàn hàn: nigbana li olukuluku yio si ni iyìn tirẹ̀ lọdọ Ọlọrun.

Ka pipe ipin 1. Kor 4

Wo 1. Kor 4:5 ni o tọ