Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kor 4:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awa jẹ aṣiwere nitori Kristi, ṣugbọn ẹnyin jẹ ọlọgbọ́n ninu Kristi; awa jẹ alailera, ṣugbọn ẹnyin jẹ alagbara; ẹnyin jẹ ọlọlá, ṣugbọn awa jẹ ẹni ẹ̀gan.

Ka pipe ipin 1. Kor 4

Wo 1. Kor 4:10 ni o tọ