Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kor 15:58 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ẹnyin ará mi olufẹ ẹ mã duro ṣinṣin, laiyẹsẹ, ki ẹ mã pọ̀ si i ni iṣẹ Oluwa nigbagbogbo, niwọn bi ẹnyin ti mọ̀ pe iṣẹ nyin kì iṣe asan ninu Oluwa.

Ka pipe ipin 1. Kor 15

Wo 1. Kor 15:58 ni o tọ