Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kor 15:24-26 Yorùbá Bibeli (YCE)

24. Nigbana ni opin yio de, nigbati o ba ti fi ijọba fun Ọlọrun ani Baba; nigbati o ba ti mu gbogbo aṣẹ ati gbogbo ọla ati agbara kuro.

25. Nitori on kò le ṣaima jọba titi yio fi fi gbogbo awọn ọta sabẹ ẹsẹ rẹ̀.

26. Ikú ni ọtá ikẹhin ti a ó parun.

Ka pipe ipin 1. Kor 15