Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kor 15:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nipa õre-ọfẹ Ọlọrun, mo ri bi mo ti ri: õre-ọfẹ rẹ̀ ti a fifun mi kò si jẹ asan; ṣugbọn mo ṣiṣẹ lọpọlọpọ jù gbogbo wọn lọ: ṣugbọn kì iṣe emi, bikoṣe õre-ọfẹ Ọlọrun ti o wà pẹlu mi.

Ka pipe ipin 1. Kor 15

Wo 1. Kor 15:10 ni o tọ