Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kor 14:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina awọn ahọn jasi àmi kan, kì iṣe fun awọn ti o gbagbọ́, bikoṣe fun awọn alaigbagbọ́: ṣugbọn isọtẹlẹ kì iṣe fun awọn ti kò gbagbọ́, bikoṣe fun awọn ti o gbagbọ́.

Ka pipe ipin 1. Kor 14

Wo 1. Kor 14:22 ni o tọ