Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kor 10:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. NITORI emi kò fẹ ki ẹnyin ki o ṣe alaimọ̀, ara, bi gbogbo awọn baba wa ti wà labẹ awọsanma, ti gbogbo wọn si là okun já;

2. Ti a si baptisi gbogbo wọn si Mose ninu awọsanma ati ninu okun;

3. Ti gbogbo wọn si ti jẹ onjẹ ẹmí kanna;

Ka pipe ipin 1. Kor 10