Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kor 1:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori Kristi kò rán mi lọ ibaptisi, bikoṣe lati wãsu ihinrere: kì iṣe nipa ọgbọ́n ọ̀rọ, ki a máṣe sọ agbelebu Kristi di alailagbara.

Ka pipe ipin 1. Kor 1

Wo 1. Kor 1:17 ni o tọ