Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Joh 3:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹniti o ba si pa ofin rẹ̀ mọ́ ngbé inu rẹ̀, ati on ninu rẹ̀. Ati nipa eyi li awa mọ̀ pe o ngbé inu wa, nipa Ẹmí ti o fifun wa.

Ka pipe ipin 1. Joh 3

Wo 1. Joh 3:24 ni o tọ