Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Joh 3:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Olufẹ, ọmọ Ọlọrun li awa iṣe nisisiyi, a kò si ti ifihàn bi awa ó ti ri: awa mọ pe, nigbati a bá fihan, a ó dabi rẹ̀; nitori awa o ri i ani bi on ti ri.

Ka pipe ipin 1. Joh 3

Wo 1. Joh 3:2 ni o tọ