Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Joh 1:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eyiti awa ti ri, ti awa si ti gbọ́ li awa nsọ fun nyin, ki ẹnyin pẹlu ki o le ní ìdapọ pẹlu wa: nitõtọ ìdapọ wa si mbẹ pẹlu Baba, ati pẹlu Ọmọ rẹ̀ Jesu Kristi.

Ka pipe ipin 1. Joh 1

Wo 1. Joh 1:3 ni o tọ