Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Gal 3:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ ki ha li ofin? a fi kun u nitori irekọja titi irú-ọmọ ti a ti ṣe ileri fun yio fi de; a si ti ipasẹ awọn angẹli ṣe ìlana rẹ̀ lati ọwọ́ alarina kan wá.

Ka pipe ipin Gal 3

Wo Gal 3:19 ni o tọ