Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Gal 3:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

ẸNYIN alaironu ara Galatia, tani ha tàn nyin jẹ, ki ẹnyin ki o máṣe gbà otitọ gbọ́, li oju ẹniti a fi Jesu Kristi hàn gbangba lãrin nyin li ẹniti a kàn mọ agbelebu.

Ka pipe ipin Gal 3

Wo Gal 3:1 ni o tọ