Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Gal 2:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati nigbati Jakọbu, ati Kefa, ati Johanu, awọn ẹniti o dabi ọwọ̀n, woye ore-ọfẹ ti a fifun mi, nwọn si fi ọwọ́ ọtún ìdapọ fun emi ati Barnaba, pe ki awa ki o mã lọ sọdọ awọn Keferi, ati awọn sọdọ awọn onila.

Ka pipe ipin Gal 2

Wo Gal 2:9 ni o tọ