Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Gal 2:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

A ti kàn mi mọ agbelebu pẹlu Kristi: ṣugbọn mo wà lãye, sibẹ ki iṣe emi mọ́, ṣugbọn Kristi wà lãye ninu mi: wiwà ti mo si wà lãye ninu ara, mo wa lãye ninu igbagbọ Ọmọ Ọlọrun, ẹniti o fẹ mi, ti o si fi on tikararẹ̀ fun mi.

Ka pipe ipin Gal 2

Wo Gal 2:20 ni o tọ