Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Gal 2:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ti a mọ̀ pe a ko da ẹnikẹni lare nipa iṣẹ ofin, bikoṣe nipa igbagbọ́ ninu Jesu Kristi, ani awa na gbà Jesu Kristi gbọ́, ki a ba le da wa lare nipa igbagbọ́ ti Kristi, kì si iṣe nipa iṣẹ ofin: nitoripe nipa iṣẹ ofin kò si enia kan ti a o dalare.

Ka pipe ipin Gal 2

Wo Gal 2:16 ni o tọ