Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Gal 2:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nigbati mo ri pe nwọn kò rìn dẽdẽ gẹgẹ bi otitọ ihinrere, mo wi fun Peteru niwaju gbogbo wọn pe, Bi iwọ, ti iṣe Ju, ba nrìn gẹgẹ bi ìwa awọn Keferi, laiṣe bi awọn Ju, ẽṣe ti iwọ fi nfi agbara mu awọn Keferi lati mã rìn bi awọn Ju?

Ka pipe ipin Gal 2

Wo Gal 2:14 ni o tọ