Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Filp 4:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mo si bẹ ọ pẹlu, bi alajọru-ajaga mi tõtọ, ran awọn obinrin wọnni lọwọ, nitori nwọn mba mi ṣiṣẹ pọ̀ ninu ihinrere, ati Klementi pẹlu, ati awọn olubaṣiṣẹ mi iyoku pẹlu, orukọ awọn ti mbẹ ninu iwe ìye.

Ka pipe ipin Filp 4

Wo Filp 4:3 ni o tọ