Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Filp 4:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn mo ni ohun gbogbo, mo si ti di pupọ: mo si kún nigbati mo ti gbà nkan wọnni ti a ti rán lati ọdọ nyin wá lọwọ Epafroditu, ọrẹ olõrùn didùn, ẹbọ itẹwọgbà, ti iṣe inu didùn gidigidi si Ọlọrun.

Ka pipe ipin Filp 4

Wo Filp 4:18 ni o tọ