Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Efe 5:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoripe ọkọ ni iṣe ori aya, gẹgẹ bi Kristi ti ṣe ori ijọ enia rẹ̀: on si ni Olugbala ara.

Ka pipe ipin Efe 5

Wo Efe 5:23 ni o tọ