Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sek 9:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si ke kẹkẹ́ kuro ni Efraimu, ati ẹṣin kuro ni Jerusalemu, a o si ké ọrun ogun kuro: yio si sọ̀rọ alafia si awọn keferi: ijọba rẹ̀ yio si jẹ lati okun de okun, ati lati odo titi de opin aiye.

Ka pipe ipin Sek 9

Wo Sek 9:10 ni o tọ