Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sek 8:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi pe, Jẹ ki ọwọ nyin ki o le, ẹnyin ti ngbọ́ ọ̀rọ wọnyi li ọjọ wọnyi li ẹnu awọn woli ti o wà li ọjọ ti a fi ipilẹ ile Oluwa awọn ọmọ-ogun lelẹ, ki a ba le kọ́ tempili.

Ka pipe ipin Sek 8

Wo Sek 8:9 ni o tọ