Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sek 8:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi pe; Ãwẹ̀ oṣù kẹrin, ati ti oṣù karun, ati ãwẹ̀ oṣù keje, ati ti ẹkẹwa, yio jẹ ayọ̀, ati didùn inu, ati apejọ ariya fun ile Juda; nitorina ẹ fẹ́ otitọ ati alafia.

Ka pipe ipin Sek 8

Wo Sek 8:19 ni o tọ