Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sek 8:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio si ṣe, gẹgẹ bi ẹnyin ti jẹ egún lãrin awọn keferi, ẹnyin ile Juda, ati ile Israeli, bẹ̃li emi o gbà nyin silẹ; ẹnyin o si jẹ ibukún: ẹ má bẹ̀ru, ṣugbọn jẹ ki ọwọ nyin ki o le.

Ka pipe ipin Sek 8

Wo Sek 8:13 ni o tọ