Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sek 5:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wi fun mi pe, Eyi ni ègun ti o jade lọ si gbogbo ilẹ aiye: nitori gbogbo awọn ti o ba jale ni a o ke kuro lati ihin lọ nipa rẹ̀; gbogbo awọn ti o ba si bura ni a o ke kuro lati ihin lọ nipa rẹ̀.

Ka pipe ipin Sek 5

Wo Sek 5:3 ni o tọ