Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sek 4:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wi fun mi pe, Kini iwọ ri? Mo si wipe, mo wò, si kiyesi i, ọ̀pa fitilà ti gbogbo rẹ̀ jẹ wurà, pẹlu kòjo rẹ̀ lori rẹ̀, pẹlu fitilà meje rẹ̀ lori rẹ̀, ati àrọ meje fun fitilà mejeje, ti o wà lori rẹ̀:

Ka pipe ipin Sek 4

Wo Sek 4:2 ni o tọ