Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sek 13:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio si ṣe li ọjọ na, li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi, li emi o ke orukọ awọn òriṣa kuro ni ilẹ na, a kì yio si ranti wọn mọ: ati pẹlu emi o mu awọn woli ati awọn ẹmi aimọ́ kọja kuro ni ilẹ na.

Ka pipe ipin Sek 13

Wo Sek 13:2 ni o tọ