Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sek 10:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Efraimu yio si ṣe bi alagbara, ọkàn wọn yio si yọ̀ bi ẹnipe nipa ọti-waini: ani awọn ọmọ wọn yio ri i, nwọn o si yọ̀, inu wọn o si dùn si Oluwa.

Ka pipe ipin Sek 10

Wo Sek 10:7 ni o tọ