Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sek 10:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori awọn oriṣa ti nsọ̀rọ asan, awọn alafọṣẹ si ti ri eké, nwọn si ti rọ́ alá eké; nwọn ntù ni ni inu lasan, nitorina nwọn ba ti wọn lọ bi ọwọ́ ẹran, a ṣẹ wọn niṣẹ, nitori darandaran kò si.

Ka pipe ipin Sek 10

Wo Sek 10:2 ni o tọ