Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sek 1:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. LI oṣù kẹjọ, li ọdun keji Dariusi, li ọ̀rọ Oluwa tọ̀ Sekariah wá, ọmọ Berekiah ọmọ Iddo woli, pe,

2. Oluwa ti binu pupọ̀ si awọn baba nyin.

Ka pipe ipin Sek 1