Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sef 3:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn iyokù Israeli kì yio hùwa ibi, bẹ̃ni nwọn kì yio sọ̀rọ eke, bẹ̃ni a kì yio ri ahọn arekerekè li ẹnu wọn: ṣugbọn nwọn o jẹun nwọn o si dubulẹ, ẹnikan kì yio si dẹ̀ruba wọn.

Ka pipe ipin Sef 3

Wo Sef 3:13 ni o tọ