Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sef 2:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Egbe ni fun awọn ẹniti ngbe agbègbe okun, orilẹ-ède awọn ara Kereti! ọ̀rọ Oluwa dojukọ nyin; iwọ Kenaani, ilẹ awọn ara Filistia, emi o tilẹ pa ọ run, ti ẹnikan kì yio gbe ibẹ̀ mọ.

Ka pipe ipin Sef 2

Wo Sef 2:5 ni o tọ