Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Rut 4:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo awọn enia ti o wà li ẹnu-bode, ati awọn àgbagba, si wipe, Awa ṣe ẹlẹri. Ki OLUWA ki o ṣe obinrin na ti o wọ̀ ile rẹ bi Rakeli ati bi Lea, awọn meji ti o kọ ile Israeli: ki iwọ ki o si jasi ọlọlá ni Efrata, ki o si jasi olokikí ni Betilehemu.

Ka pipe ipin Rut 4

Wo Rut 4:11 ni o tọ