Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Rut 1:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Naomi si wi fun awọn aya-ọmọ rẹ̀ mejeji pe, Ẹ lọ, ki olukuluku pada lọ si ile iya rẹ̀: ki OLUWA ki o ṣe rere fun nyin, gẹgẹ bi ẹnyin ti ṣe fun awọn okú, ati fun mi.

Ka pipe ipin Rut 1

Wo Rut 1:8 ni o tọ