Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Rut 1:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Orukọ ọkunrin na a si ma jẹ́ Elimeleki, orukọ obinrin rẹ̀ a si ma jẹ́ Naomi, orukọ awọn ọmọ rẹ̀ ọkunrin mejeji a si ma jẹ́ Maloni ati Kilioni, awọn ara Efrata ti Betilehemu-juda. Nwọn si wá si ilẹ Moabu, nwọn si ngbé ibẹ̀.

Ka pipe ipin Rut 1

Wo Rut 1:2 ni o tọ