Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Owe 27:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọrẹ́ rẹ ati ọrẹ́ baba rẹ, máṣe kọ̀ silẹ, bẹ̃ni ki iwọ ki o máṣe lọ si ile arakunrin li ọjọ idãmu rẹ: nitoripe aladugbo ti o sunmọ ni, o san jù arakunrin ti o jina rere lọ.

Ka pipe ipin Owe 27

Wo Owe 27:10 ni o tọ