Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Owe 24:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ti iwọ si wipe, wò o, awa kò mọ̀ ọ; kò ha jẹ pe ẹniti ndiwọ̀n ọkàn nkiyesi i? ati ẹniti npa ọkàn rẹ mọ́, on li o mọ̀, yio si san a fun enia gẹgẹ bi iṣẹ rẹ̀.

Ka pipe ipin Owe 24

Wo Owe 24:12 ni o tọ