Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Owe 24:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. IWỌ máṣe ilara si awọn enia buburu, bẹ̃ni ki o má si ṣe fẹ lati ba wọn gbe.

2. Nitoriti aiya wọn ngbiro iparun, ète wọn si nsọ̀rọ ìwa-ika.

Ka pipe ipin Owe 24