Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Owe 23:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbọ́, iwọ ọmọ mi, ki iwọ ki o si gbọ́n, ki iwọ ki o si ma tọ́ aiya rẹ si ọ̀na titọ.

Ka pipe ipin Owe 23

Wo Owe 23:19 ni o tọ