Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Owe 2:21-22 Yorùbá Bibeli (YCE)

21. Nitoripe ẹni-iduroṣinṣin ni yio joko ni ilẹ na, awọn ti o pé yio si ma wà ninu rẹ̀.

22. Ṣugbọn awọn enia buburu li a o ke kuro ni ilẹ aiye, ati awọn olurekọja li a o si fàtu kuro ninu rẹ̀.

Ka pipe ipin Owe 2