Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Owe 13:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọrọ̀ ti a fi ìwa-asan ni yio fàsẹhin; ṣugbọn ẹniti o fi iṣẹ-ọwọ kojọ ni yio ma pọ̀ si i.

Ka pipe ipin Owe 13

Wo Owe 13:11 ni o tọ