Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Owe 12:26-28 Yorùbá Bibeli (YCE)

26. Olododo tọ́ aladugbo rẹ̀ si ọ̀na; ṣugbọn ọ̀na awọn enia buburu tàn wọn jẹ.

27. Ọlẹ enia kò mu ohun ọdẹ rẹ̀; ṣugbọn lati jẹ alãpọn enia, ọrọ̀ iyebiye ni.

28. Li ọ̀na olododo ni ìye; ikú kò si loju ọ̀na otitọ.

Ka pipe ipin Owe 12