Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oni 9:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bakanna li ohun gbogbo ri fun gbogbo wọn: ohun kanna li o nṣe si olododo, ati si ẹni buburu; si enia rere, ati si mimọ́ ati si alaimọ́; si ẹniti nrubọ, ati si ẹniti kò rubọ: bi enia rere ti ri, bẹ̃ li ẹ̀lẹṣẹ; ati ẹniti mbura bi ẹniti o bẹ̀ru ibura.

Ka pipe ipin Oni 9

Wo Oni 9:2 ni o tọ