Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oni 9:17-18 Yorùbá Bibeli (YCE)

17. A ngbọ́ ọ̀rọ ọlọgbọ́n enia ni pẹlẹ jù igbe ẹniti njẹ olori ninu awọn aṣiwère.

18. Ọgbọ́n san jù ohun-elo ogun: ṣugbọn ẹ̀lẹṣẹ kan o ba ohun didara pupọ jẹ.

Ka pipe ipin Oni 9