Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oni 8:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo nkan wọnyi ni mo ri, mo si fiyè si iṣẹ gbogbo ti a nṣe labẹ õrùn: ìgba kan mbẹ ninu eyi ti ẹnikan nṣe olori ẹnikeji fun ifarapa rẹ̀.

Ka pipe ipin Oni 8

Wo Oni 8:9 ni o tọ