Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oni 8:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni mo wò gbogbo iṣẹ Ọlọrun, pe enia kò le ridi iṣẹ ti a nṣe labẹ õrùn: nitoripe bi enia tilẹ gbiyanju ati wadi rẹ̀, sibẹ kì yio le ri i; ati pẹlupẹlu bi ọlọgbọ́n enia rò lati wadi rẹ̀, sibẹ kì yio lè ridi rẹ̀.

Ka pipe ipin Oni 8

Wo Oni 8:17 ni o tọ