Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Oni 8:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni mo yìn iré, nitori enia kò ni ohun rere labẹ õrùn jù jijẹ ati mimu, ati ṣiṣe ariya: nitori eyini ni yio ba a duro ninu lãla rẹ̀ li ọjọ aiye rẹ̀, ti Ọlọrun fi fun u labẹ õrùn.

Ka pipe ipin Oni 8

Wo Oni 8:15 ni o tọ